Terms and text shown below represent Sola’s contributions to TermWiki.com, a free terminology website and knowledge resource for the translation community.
A legal contract signed by all employees to guarantee that they will not reveal the company's confidential and propriety information.
Iwe ti gbogbo osise ti owo bo pe awon ko ni tu asiri ikoiko ti ile ise naa sita
The fifth book of the Old Testament.
Iwe ikarun un ti Majemu Laelae
a person who writes articles for newspapers and magazines
eni ti o nko awon apileko for awon iwe iroyin ati awon iwe iroyin atigbadegba
The week preceding Easter, beginning with Palm (Passion) Sunday, called the "Great Week" in the liturgies of the Eastern Churches. It marks the Church's annual celebration of the events of Christ's Passion, death, and Resurrection, culminating in the Paschal ...
Ose ti o nsaaju Odun Ajinde, ti o nbere pelu Isinmi Ope (Ijiya), ti a npe ni "Ose Nla" ninu iwe awon Ijo ti Ila Oorun. O nsami si ayeye olodoodun ti Ijo fun Ijiya, iku ati Ajinde Kristi, ti o npari si Ijinle ti Ajinde (1169)
Whether or not employees are happy and feel fulfilled in their positions.
Boya inu awon osise dun ti ise won si te won lorun abi beeko
The wise men who came from the East to pay homage to the newborn Savior (528).
Awon amoye ti won wa lati Ila oorun lati fi ori bale fun Olugbala ti a sese bi (528)
zigazag is to move sporadically, not to move directly or normally
zigazag is to move sporadically, not to move directly or normally
evoking or tending to evoke an especially emotional response
nru nnkan soke abi o n gbiyanju lati mu esi jade, paapaa eyi ti o la itara lo.
An assessment of an employee's performance, with potential salary raises for good performance.
Sise ayewo isesi osise kan, pelu siseese afikun owo oya fun iwa rere
A guide for employees including information about the company, terms and conditions, and policies and procedures in the company.
Itoni fun awon osise, ninu eyi ti alaye nipa ile ise naa, awon ofin ati alakale, ati awon ilana ati agbekale ninu ile ise naa