Terms and text shown below represent Sola’s contributions to TermWiki.com, a free terminology website and knowledge resource for the translation community.
a person who gathers and reports news
eni ti o nsa iroyin jo ti o si nka won
Study on one’s own, learning from materials often supported by a tutor, in contrast to working in a class or attending a lecture.
Kika iwe ni aaye ara eni, kiko eko lati ara awon ohun elo eyi ti oluko kan saba maa nse iranlowo, ni iyato si sise ise ninu yara ikawe tabi lilo si ibi ti a ti ngba idanilekoo
Control of a display from a remote and/or central location via a communications network.
Idari ifihan kan lati ona jijin/abi lati ojuko kan nipase ero alatagba ibanisoro kan
Documentation intended to help a student learn successfully but not to teach him/her
Akosile ti a pete re lati ran akekoo kan lowo lati kawe pelu aseyori sugbon ti ki ise lati ko o
The week preceding Easter, beginning with Palm (Passion) Sunday, called the "Great Week" in the liturgies of the Eastern Churches. It marks the Church's annual celebration of the events of Christ's Passion, death, and Resurrection, culminating in the Paschal ...
Ose ti o nsaaju Odun Ajinde, ti o nbere pelu Isinmi Ope (Ijiya), ti a npe ni "Ose Nla" ninu iwe awon Ijo ti Ila Oorun. O nsami si ayeye olodoodun ti Ijo fun Ijiya, iku ati Ajinde Kristi, ti o npari si Ijinle ti Ajinde (1169)
The virtue by which a Christian acknowledges that God is the author of all good. Humility avoids inordinate ambition or pride, and provides the foundation for turning to God in prayer (2559). Voluntary humility can be described as "poverty of spirit" (2546).
Iwa ti Kristiani fi ngba pe Olorun ni olupilese ohun rere gbogbo Irele maa nyera fun ilepa ni dandan abi igberaga, ti o si npese ipile fun didoju ko Olorun ninu adura (2559) Irele atokanwa ni a le juwe si "titosi ninu emi" (2546)
The sinner who repents of sin and seeks forgiveness (1451). In the early Church, public sinners belonged to an "order of penitents," who did public penance for their sins, often for years (1447). Penitential acts or practices refer to those which dispose one ...
Elese naa ti o nronupiwada ti o si nwa idariji (1451) Ninu ijo ibere, awon ti o dese ni gbangba je ara "egbe awon ti o ronupiwada" ti won nronupiwada ni gbangba fun ese won, ni opolopo igba fun opolopo odun (1447) Awon ise abi asa ironupiwada ntoka si nje ki ...
The sinner who repents of sin and seeks forgiveness (1451). In the early Church, public sinners belonged to an "order of penitents," who did public penance for their sins, often for years (1447). Penitential acts or practices refer to those which dispose one ...
Elese naa ti o nronupiwada ti o si nwa idariji (1451) Ninu ijo ibere, awon ti o dese ni gbangba je ara "egbe awon ti o ronupiwada" ti won nronupiwada ni gbangba fun ese won, ni opolopo igba fun opolopo odun (1447) Awon ise abi asa ironupiwada ntoka si nje ki ...
The visit of the angel Gabriel to the virgin Mary to inform her that she was to be the mother of the Savior. After giving her consent to God's word, Mary became the mother of Jesus by the power of the Holy Spirit (484, 494).
Ibewo ti angeli Gabrieli se si Maria wundia lati so fun u pe oun yoo di iya Olugbala Leyin ti o fi ara mo oro Olorun, Maria di iya Jesu nipa agbara Emi Mimo (484, 494)
A quiz is a form of game or mind sport in which the players (as individuals or in teams) attempt to answer questions correctly. Quizzes are also brief assessments used in education and similar fields to measure growth in knowledge, abilities, and/or skills.
Ibeere ati idahun je ere idaraya kan tabi ere idaraya atinuwa ninu eyi ti awon olukopa [bi awon olodonni tabi bi awon egbe] n gbiyanju lati dahun awon ibeere ni ona ti o tona. Awon ibeere ati idahun tun je awon idanwo ranpe ti a nlo ninu eto eko ati awon ona ...