portrait

Sola Agboola

Ado Ekiti, Nigeria

Translate From: English (EN)

Translate To: Yoruba (YO)

991

Words Translated

0

Terms Translated

Sola’s Selected Translation Work

Terms and text shown below represent Sola’s contributions to TermWiki.com, a free terminology website and knowledge resource for the translation community.

English (EN)culture

In an organization, the shared attitudes, values and goals of that organization.

Yoruba (YO)asa

Ni ile ise kan, awon iwa ti o kari, awon ohun ti won ponle ati awon afojusun ile ise yen

Business services; Human resources

English (EN)study guide

Documentation intended to help a student learn successfully but not to teach him/her

Yoruba (YO)ohun ti o n toni sona lati kawe

Akosile ti a pete re lati ran akekoo kan lowo lati kawe pelu aseyori sugbon ti ki ise lati ko o

Education; Education & training

English (EN)suicide

The willful taking of one's own life; a grievous sin against the fifth commandment. A human person is neither the author nor the supreme arbiter of his life, of which God is sovereign master (2280).

Yoruba (YO)iseku-pa-ara-eni

Fifinu-findo gba emi ara eni; ese ti o buru lodi si ofin karun Eniyan kan ki ise olupilese abi eni ti o lase julo lori aye re, eyi ti o je pe Olorun ni alase patapata (2280)

Religion; Catholic church

English (EN)for they do not know what they are doing

Father, forgive them, for they do not know what they are doing...

Yoruba (YO)nitori pe won ko mo ohun ti won nse

Baba, dari ji won, nitori pe won ko mo ohun ti won nse

Religion; Christianity

English (EN)employee satisfaction

Whether or not employees are happy and feel fulfilled in their positions.

Yoruba (YO)bi osise ti ni itelorun si

Boya inu awon osise dun ti ise won si te won lorun abi beeko

Business services; Human resources

English (EN)intensity

Also called brightness. The LED industry measures display intensity in candelas per square meter, which is also referred to as nits.

Yoruba (YO)bi nnkan ti lagbara si

A tun npe e ni bi o ti mole si. Ile ise LED nse oduwon afihan nipa bi nnkan ti lagbara si ni iwon iye kandela ti o wa ninu ayipo mita kan, ti a tun npe ni niiti.

Advertising; Billboard advertising

English (EN)quiz

A quiz is a form of game or mind sport in which the players (as individuals or in teams) attempt to answer questions correctly. Quizzes are also brief assessments used in education and similar fields to measure growth in knowledge, abilities, and/or skills.

Yoruba (YO)Ibeere ati idahun.

Ibeere ati idahun je ere idaraya kan tabi ere idaraya atinuwa ninu eyi ti awon olukopa [bi awon olodonni tabi bi awon egbe] n gbiyanju lati dahun awon ibeere ni ona ti o tona. Awon ibeere ati idahun tun je awon idanwo ranpe ti a nlo ninu eto eko ati awon ona ...

Education;

English (EN)employee evaluation

An assessment of an employee's performance, with potential salary raises for good performance.

Yoruba (YO)gbigbe osise lori iwon

Sise ayewo isesi osise kan, pelu siseese afikun owo oya fun iwa rere

Business services; Human resources

English (EN)racism

Unjust discrimination on the basis of a person's race; a violation of human dignity, and a sin against justice (1935).

Yoruba (YO)eleya-meya

Fifi aito se iyasoto nitori eya eni; tite aponle eniyan loju, ati ese si idajo ododo (1935)

Religion; Catholic church

English (EN)prudence

The virtue which disposes a person to discern the good and choose the correct means to accomplish it. One of the cardinal moral virtues that dispose the Christian to live according to the law of Christ, prudence provides the proximate guidance for the ...

Yoruba (YO)isora-eni

Iwa ti o nmu ki eniyan le mo rere ki o si yan ona ti o tona lati se e Koko kan lara awon iwa rere ti o nmu ki Kristiani le gbe igbe-aye gege bi ofin Kristi, isora-eni nfun ni ni itosona lerefee fun isedajo ti eri-okan (1806)

Religion; Catholic church